Okan Bale

Angelique Kidjo

Compositor: Não Disponível

Okan balè o
Okan balè o
Okan balè o
Okan balè o

Emi ni kan ko ló wa la yé
Omo dada lé mi
Moni ebí pupó
Momo gbogbó ibí témi laye
Iri si dada ni témi e gbo o

Momo pe éfe ran mí, éje ki n mo
Dupé fun yin
Ife yin fun mi layo
Mo fe ki aye temi ko da
Iya mi o, pélú baba mí (baba mí)
Awon aburo mi n ko? (Baba mí)
Mo n de dupé fun olúwa o (baba mí)
To fun mí lébí tóda yi (baba mi)

Mo n dupe fun ayé yí o
Ododún maré mo n dupe

Okan balè o
Okan balè o

Eni ti o ba nífe ninu ayé
Pelú ebí dada óluwaré ajiya
Gbogbo wa ninu aya wa ifé
Kadúpe ti awa ba ri ife dada

Momo pe éfe ran mí, éje ki n mo
Dupé fun yin
Ife yin fun mi layo, mo fe ki aye temi ko da
Iya mi o, pélú baba mí (baba mí)
Awon aburo mi n ko? (Baba mí)
Mo n de dupé fun olúwa o (baba mí)
To fun mí lébí tóda yi (baba mi)

Modupe fun ayé yí o
Ododún maré mo n dupe

©2003- 2025 lyrics.com.br · Aviso Legal · Política de Privacidade · Fale Conosco desenvolvido por Studio Sol Comunicação Digital